Nípa Alámọ̀já Yorùbá

A jẹ́ alámọ̀já èdè Yorùbá.
Gbólóhùn Ìlépa/Ìran
Wọ̀nyí ni àwọn ìran àti ìlépa wa gẹ́gẹ́ bí alámọ̀já èdè Yorùbá.

Ìlépa: Láti ṣe ìtànká, àti ìtọ́jú èdè Yorùbá àti láti mú èdè náà lọ sí ipele tí ó kàn nípa pípèsè àwọn iṣẹ́ àti ohun èlò tí yóò wúlò.

Ìran: Láti jẹ́ Alámọ̀já èdè Yorùbá tí gbogbo ènìyàn yóò mọ̀ káàkiri àgbáyé.

About Alámọ̀já Yorùbá

We are Yorùbá Language specialists.
Mission/Vision Statement
These are our goals and objectives as Yorùbá Language specialists.

Mission: To preserve and take Yorùbá Language to the next level by providing useful and relevant product and services.

Vision: To become a widely known Yorùbá Language Specialist.

Meet the Founder

Damilola Adebonojo

Dámilọ́lá Adébọ́nọ̀jọ (a.k.a Ìyá Yorùbá) is an Independent Yorùbá Language Specialist, Culture Enthusiast, Tutor, Content Creator and the founder of Alámọ̀já Yorùbá (The Yorùbá Language Service Provider).

She holds a Bachelor Degree in Yoruba and Communication Arts from the prestigious Lagos State University and a Master degree (in view) in Yorùbá Literature and Culture.

She started out as a freelance Translator in 2014, she translated write-ups across all genres from English to Yorùbá Language, out of which includes the soon to be published translation of the novella “Out of His Mind” written by Báyọ̀ Adebowale with the Yorùbá title “Jíjọ ló Jọ”.

Over the years, she has worked with individuals, businesses and organizations to manage their Yorùbá-based projects ranging from Translations, Transcriptions, Voice-overs, Interpretations, Educational projects (researches, thesis) to Movie Subtitles. Over 30 Yorùbá Movies has been subtitled by Ìyá Yorùbá ranging from Ojúlówó ọmọ, Atẹgun, to Kuranga and many others.

She tutors and mentors people of different ages and tribes across the globe on how to fluently Speak and perfectly Read/Write in Yorùbá Language.

Would you like her to handle any of your projects or tutor you/your children in Yorùbá?
Contact her on iyayorubagidi@gmail.com
Or on Whatsapp: 08128958435

You can also follow her on social media platforms:
Facebook: Ìyá Yorùbá
Twitter: @ìyáYorùbá
Instagram: Iya_Yoruba

Do you want to partner, volunteer, advertise or help us to improve in what we do? Kindly send us a message by filling the form below. Or send us a mail directly!

(Your Name)
(Your Email)
(Subject)
(Message)