Àṣà (Culture)

Iṣẹ́ Ṣíṣe ní Ilẹ̀ Yorùbá

“Iṣẹ́ àgbẹ̀ ni iṣẹ́ ilẹ̀ wá”. – A Yorùbá song Ní ayé àtijó, kò sí àwọn iṣẹ́ àwòṣe (apprenticeship) lọ títí. Àwọn iṣẹ́ tí ó wọ́pọ̀, tí wọ́n sì ṣe pàtàkì lásìkò náà ni àwọn iṣẹ́ ìṣẹ̀ǹbáyé Yorùbá. Èyí ni àwọn iṣẹ́ tí ìdílé kọ̀ọ̀kan ń ṣe, tí àwọn ọmọ sì máa ń jogúnbá lọ́wọ́

Iṣẹ́ Ṣíṣe ní Ilẹ̀ Yorùbá Read More »

Scroll to Top