Yorùbá Bird Names: Duck
Duck is called “Pẹ́pẹ́yẹ” in Yorùbá Language
Yorùbá Bird Names: Duck Read More »
Duck is called “Pẹ́pẹ́yẹ” in Yorùbá Language
Yorùbá Bird Names: Duck Read More »
Àìná jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn orúkọ àmútọ̀runwá Yorùbá tí wọ́n máa ń sọ ọmọ tí ó bá gbé ìwọ́ rẹ kọ́rùn nígbà tí wọ́n bá bí i. Orúkọ náà túmọ̀ sí “Ẹni tí a ò gbọdọ̀ nà”. Iṣẹ́ kan náà ni orúkọ Òjó àti Àìná ń ṣe, ọmọkùnrin nìkan ni a lè sọ ní Òjó.
The Yorùbá Name “ÀÌNÁ” Read More »