Àṣà (Culture)

ÈṢÙ IS NOT SATAN; WHO ÈṢÙ IS AND WHO HE IS NOT

Posted on

We joined joined the #esuisnotsatan awareness late December 2018. The reason for the campaign was to let people know what Èṣù is and what it is not and to encourage people to own up to their mistakes without saying “Iṣẹ́ èṣù ni”. There have been misconceptions about Èṣù, what people think it is. In this […]

Àṣà (Culture)

Iṣẹ́ Ṣíṣe ní Ilẹ̀ Yorùbá

Posted on

“Iṣẹ́ àgbẹ̀ ni iṣẹ́ ilẹ̀ wá”. – A Yorùbá song Ní ayé àtijó, kò sí àwọn iṣẹ́ àwòṣe (apprenticeship) lọ títí. Àwọn iṣẹ́ tí ó wọ́pọ̀, tí wọ́n sì ṣe pàtàkì lásìkò náà ni àwọn iṣẹ́ ìṣẹ̀ǹbáyé Yorùbá. Èyí ni àwọn iṣẹ́ tí ìdílé kọ̀ọ̀kan ń ṣe, tí àwọn ọmọ sì máa ń jogúnbá lọ́wọ́ […]

Technology

Type Yorùbá Language with ease on Microsoft Word

Posted on

Do you know you can type Yorùbá words on Microsoft Word and insert the tone-marks without the use of any special software? Click on the link below to watch the video. Please don’t forget to subscribe to our YouTube channel for relevant videos like this. https://m.youtube.com/watch?v=HiuSHZVANas

Uncategorized

The Yorùbá Name “ÀÌNÁ”

Posted on

Àìná jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn orúkọ àmútọ̀runwá Yorùbá tí wọ́n máa ń sọ ọmọ tí ó bá gbé ìwọ́ rẹ kọ́rùn nígbà tí wọ́n bá bí i. Orúkọ náà túmọ̀ sí “Ẹni tí a ò gbọdọ̀ nà”. Iṣẹ́ kan náà ni orúkọ Òjó àti Àìná ń ṣe, ọmọkùnrin nìkan ni a lè sọ ní Òjó. […]

Ìtàn (History)

The Origin of Gudu Gudu Méje àti Yàyà Mẹ́fà

Posted on

During the colonial period, some Ibadan Chiefs went to a meeting with Mr Hezekiah Shunklebottom, the notoriously difficult British district officer. In the course of the meeting the district officer was happy with what the Ibadan chiefs had to report and present via an interpreter. He kept nodding and saying “good good good good good […]